Friday, June 16, 2017

Owó ti te àwon àpapò tí a mò sí Boko Haram





Owó ti te àwon àpapò tí a mò sí Boko Haram tí won ń dógbón se bíi fúlàní darandaran ní ìlú Edo



NAN, Otaru ti ilè Auchi, Alhaji Aliru H. Momoh , ní ìlú Edo, ti kéde ní ojó ajé bí owó se te okòó lé mérin( 24) àwon afurasí Boko Haram tí won ń se bíi fúlàní darandaran ní agbègbè náà tí owó àwon ológun ti bà.

       Oba so fún àwon oníròyìn ní ààfin rè ní Auchi ní àgbáríjo ìjoba ìbílè ìwò oòrùn ní ìjoba ìbílè náà, wípé apàse ilé-ìwé ológun orílè èdè Nàìjíríà NICOHO ní agbègbè Auchi, fi tó o létí nípa mímú àwon afurasí náà. "kí ó tó di wípé o wolé, mo ti ní òrò pèlú apàse ".

 "ó fi oun tí won ń se tó mi tó mi létí àti bíwon se mú okòó lé mérin (24) àwon afurasí yi Boko Haram tí won sisé bí fúlàní darandaran ".ó so béè.

   "Apàse tún fi tó mi létí wípé àwon afurasí yí won máa darí won lo sí Benin "Oba so béè.



Ó gbé oríyìn fún apàse fún ìgbésè takuntakun tí ó gbé  láti bá àwon afurasí náà wo ìjàkadi nínú aginjù

 Ó so wípé "ètò ìdáàbòbò ní láti se àmójútó fínífíní ",

 Otaru sàpéjùwé ètò àwon darandaran lágbègbè won wípé óburú jàè so pé " A ti be àwon àgbè, papàá jùlo àwon obìnrin láti má lo sí oko ní àkókò yí.

  A fún won ní owó díè láti jé kí won máa se isé tí owó won bá fún ìgbà díè náà. Tí gbogbo rè máa fi yanjú.

   Àwon ìgbìmò ìbílè ń jùmò sisé pò pèlú àwon ológun, àwon olùdáàbòbò ìlú asì ti fi tó àwon olóde létí láti wá ònà àbáyo tó dángájíá sí òrò náà "ó fi kun



English Version

Continue bellow.





 24 Boko Haram Insurgents Operating As Fulani Herdsmen Arrested In Edo



NAN- The Otaru of Auchi Kingdom, Alhaji Aliru H. Momoh, in Edo, on Monday announced the arrest of 24 suspected Boko Haram members operating as Fulani Herdsmen in the community by the Nigerian Army.



The monarch told newsmen in his palace at Auchi, headquarters of the Estako-West local government area of the state that the commandant of the Nigeria Army School of Engineering, NICOHO, near Auchi, informed him of the arrest of the suspected insurgents.



“Shortly before you came, I had audience with the commandant.



“He informed me about what they are doing and the arrest of some 24 suspected members of Boko Haram operating under the guise of Fulani herdsmen in the community,’’ he said.



“The commandant also informed me that the suspects would be transferred to Benin,’’ the Highness said.

He commended the commandant for taking proactive steps to have taken the fight to the suspected insurgents in the forest, saying that the “issue of security needs careful planning and execution’’.



The Otaru, who described the activities of the herdsmen in the area as worrisome, said “we have asked farmers, especially the women, to stop going to the farms for now”.



“We gave them some grants to enable them to engage in petty trading in the mean time, to avoid the incessant attacks on them.



“The traditional council is collaborating with the army, security agencies, and some vigilance groups, and we have recently incorporated the hunters to help to evolve lasting solutions to the problem,’’ he added.

No comments:

Post a Comment