Friday, June 30, 2017

Àyàngbàjù! Ògbó n tarìgì gbómogbómo, Evans pe ògá olóòpá l'éjó

Àyàngbàjù! Ògbó n tarìgì gbómogbómo, Evans pe ògá olóòpá l'éjó

Oko mi fi mí sílè nítorí pé mi ò tí bímo Okàn mi ń pòrúrú Egbàmí!

Sunday, June 25, 2017

Nigerian mathematician Builds Flying F-35D prototype (Flying Drone)

Nigerian mathematician Builds Flying F-35D prototype (Flying Drone)

Friday, June 23, 2017

Ìkan Lára Àwon Ìyá Ń Dá Gbé (Single Mum) Orílè Èdè Nàìjíríà

Akékòó Odún Keta 300l Ti Oau Ti Eka Èkó 'Pharmacy' Rì Sómi

Òrékùnrin àtijó Vera Sidika fi ìhòhò rè hàn látàrí pé ó fi sílè bá olówó...

Kcee tú àsírí pé òhun ni olórin àkókò ní ìròlé èdè Nàìjíríà

Monday, June 19, 2017

Macron wins Parliament in landslide: Total failure inevitable

by Ramin Mazaheri
That headline is not even a bold statement because Macron has promised austerity and…when has austerity ever worked? It is really that simple.
There has been nearly four decades of trickle-down economics and anti-socialist policies, but there has been no promised increase in the standard of living. It has only dropped since the gains of the 1970s, the era of maximum worker power in the West.
I say the West because Iran, to give a personal example, did not have maximum worker power in the 1970s, so let’s not paint everyone all with the same brush – that’s inaccurate and only aids rampant depression in the West.

Friday, June 16, 2017

Tonto Dikeh pèlú Muhammed Lai nínú okò ojú òfurunfú

Diamond Platnumz Ti Yanjú Aáwò Tí Ó Wà Láàrin Òhun Àti Ìyá Omo Rè

Èsì Ikú Tí Ó Pa Joy Odama Akékòó Odún Kejí (200l)

Èsì Ikú Tí Ó Pa Joy Odama Akékòó Odún Kejí (200l) Ti Ilé-èkó Gíga Ifáfitì Tí Ó Wà Ní Ìpínlè Cross River -Léyìn tí a gbó èsì ikú tí ó pa Joy Odama akékòó odún kejí (200l) ti ilé-èkó gíga ifáfitì tí ó wà ní ìpínlè Cross river (university of science and technology (CRUTEC)) èyí tí ó kú ikú kàyééfi léyìn ìgbà tí ó rí Alhaji kan tí a mò sí Alhaji Usman Adamu ní ìlú Abuja ní osù kewàá odún tí ó Jojo.

       Gégé bí ìwé ìròyìn Vanguard, èsì ikú yìí tí ilé-ìwòsàn ìjoba àpapó (National hospital) ní ìlú Abuja gbé jáde , fihàn pé ikú májèlé ni arabìnrin náà kú, látàrí egbò igi olóró tí a mò sí kokeènì (cocaine). Agbó wípé arabìnrin yìí ní àìsàn okàn tí a mò sí (cardiogenic shock).  Ìyá olóògbé ,Philomena Odama, ní ìbèrè pèpè osù ti ko ìwé èbè (petition) sí ipò ààre  orílè èdè (presidency), ìgbìmò asòfin àgbà (Senate president), agbenuso ilé ìgbìmò asojú sòfin (speaker of house of representative), ògá àgbà ilé-isé olóòpá (IGP) DSS àti àwon èyà tí o ń dáàbò bo ìlú pèlú àwon tí ó wà ní ipò gíga nípa ikú omo rè. Nínú ìwé tí aya Philomena ko o se àfihàn bí eni tí won fura sí yìí ti máa ń gbé òpòlopò omoge ní èbá ònà tí ó sì máa ń se ìlérí wípé òhun o tó won ní iié-ìwé.

    Ní àkámó eni tí a fura sí yìí ní arabìnrin Joy odama kú sí. Ó sì ti gbìmò pò mó àwon olóòpá láti gbé omo náà sínú yìnyín láì fi tó àwon òbí rè létí. Àwon olóòpá ní kí àwon jáwó nínú ejó náà kí àwon sì gba egbèrún lónà egbèédógún (300,000) tí a fura sí yìí gbé fún won. Wípé àwon kò sì le è dá ejó nítorí gbajúmò tí ó túmò sí wípé òtòkùlú ni…….English Version

 Continue bellowAutopsy report shows 200 level student of the Cross Rivers state University, Joy Odama, died of cocaine poison The autopsy report for Joy Odama, the 200 level student of the Cross River State University of Science and Technology, CRUTEC, who died mysteriously after she went to visit a certain Alhaji Usman Adamu, in Abuja last December, has been released. According to Vanguard, the autopsy report released by the National Hospital, Abuja, showed she died of acute cocaine poison. Joy was said to have suffered cardiogenic shock secondary to diffusion before she died. The report reads in part:“The cause of death was traced to cardiogenic shock secondary to diffusion, myocardial infaration secondary to possible acute cocaine poison.” Mother of the deceased, Philomena Odama, had earlier this month, petitioned the presidency, the senate president, Speaker of the House of Representatives, IGP, DSS and other top security agencies, over the death of her daughter. Mrs Philomena in her petition, indicated the the suspect had invited her daughter alongside other young girls to his house and promised to sponsor their education. Joy died in his custody and the suspect allegedly connived with the police to embalm her without her parents consent. The police allegedly told them to hands off the case and collect N300, 000 the suspect was offering them, saying they can not get justice as he is well connected in the society. -

Laura Ikeji àti Ogbonaya Kanu kí omo tuntun

Owó ti te àwon àpapò tí a mò sí Boko Haram

Owó ti te àwon àpapò tí a mò sí Boko Haram tí won ń dógbón se bíi fúlàní darandaran ní ìlú EdoNAN, Otaru ti ilè Auchi, Alhaji Aliru H. Momoh , ní ìlú Edo, ti kéde ní ojó ajé bí owó se te okòó lé mérin( 24) àwon afurasí Boko Haram tí won ń se bíi fúlàní darandaran ní agbègbè náà tí owó àwon ológun ti bà.

       Oba so fún àwon oníròyìn ní ààfin rè ní Auchi ní àgbáríjo ìjoba ìbílè ìwò oòrùn ní ìjoba ìbílè náà, wípé apàse ilé-ìwé ológun orílè èdè Nàìjíríà NICOHO ní agbègbè Auchi, fi tó o létí nípa mímú àwon afurasí náà. "kí ó tó di wípé o wolé, mo ti ní òrò pèlú apàse ".

 "ó fi oun tí won ń se tó mi tó mi létí àti bíwon se mú okòó lé mérin (24) àwon afurasí yi Boko Haram tí won sisé bí fúlàní darandaran ".ó so béè.

   "Apàse tún fi tó mi létí wípé àwon afurasí yí won máa darí won lo sí Benin "Oba so béè.Ó gbé oríyìn fún apàse fún ìgbésè takuntakun tí ó gbé  láti bá àwon afurasí náà wo ìjàkadi nínú aginjù

 Ó so wípé "ètò ìdáàbòbò ní láti se àmójútó fínífíní ",

 Otaru sàpéjùwé ètò àwon darandaran lágbègbè won wípé óburú jàè so pé " A ti be àwon àgbè, papàá jùlo àwon obìnrin láti má lo sí oko ní àkókò yí.

  A fún won ní owó díè láti jé kí won máa se isé tí owó won bá fún ìgbà díè náà. Tí gbogbo rè máa fi yanjú.

   Àwon ìgbìmò ìbílè ń jùmò sisé pò pèlú àwon ológun, àwon olùdáàbòbò ìlú asì ti fi tó àwon olóde létí láti wá ònà àbáyo tó dángájíá sí òrò náà "ó fi kunEnglish Version

Continue bellow.

 24 Boko Haram Insurgents Operating As Fulani Herdsmen Arrested In EdoNAN- The Otaru of Auchi Kingdom, Alhaji Aliru H. Momoh, in Edo, on Monday announced the arrest of 24 suspected Boko Haram members operating as Fulani Herdsmen in the community by the Nigerian Army.The monarch told newsmen in his palace at Auchi, headquarters of the Estako-West local government area of the state that the commandant of the Nigeria Army School of Engineering, NICOHO, near Auchi, informed him of the arrest of the suspected insurgents.“Shortly before you came, I had audience with the commandant.“He informed me about what they are doing and the arrest of some 24 suspected members of Boko Haram operating under the guise of Fulani herdsmen in the community,’’ he said.“The commandant also informed me that the suspects would be transferred to Benin,’’ the Highness said.

He commended the commandant for taking proactive steps to have taken the fight to the suspected insurgents in the forest, saying that the “issue of security needs careful planning and execution’’.The Otaru, who described the activities of the herdsmen in the area as worrisome, said “we have asked farmers, especially the women, to stop going to the farms for now”.“We gave them some grants to enable them to engage in petty trading in the mean time, to avoid the incessant attacks on them.“The traditional council is collaborating with the army, security agencies, and some vigilance groups, and we have recently incorporated the hunters to help to evolve lasting solutions to the problem,’’ he added.

Tuesday, June 13, 2017

Odomokunrin Kan Ni Orile Ede Naijiria Ati Ara Binrin Oyinbo

Won ge apa ati ori arakunrin kan nitori ija ile ni ipinle delta

Sunday, June 4, 2017

A king or a disgrace to kingship in Yoruba, SW Nigeria ?