Friday, June 16, 2017

Èsì Ikú Tí Ó Pa Joy Odama Akékòó Odún Kejí (200l)

Èsì Ikú Tí Ó Pa Joy Odama Akékòó Odún Kejí (200l) Ti Ilé-èkó Gíga Ifáfitì Tí Ó Wà Ní Ìpínlè Cross River -Léyìn tí a gbó èsì ikú tí ó pa Joy Odama akékòó odún kejí (200l) ti ilé-èkó gíga ifáfitì tí ó wà ní ìpínlè Cross river (university of science and technology (CRUTEC)) èyí tí ó kú ikú kàyééfi léyìn ìgbà tí ó rí Alhaji kan tí a mò sí Alhaji Usman Adamu ní ìlú Abuja ní osù kewàá odún tí ó Jojo.

       Gégé bí ìwé ìròyìn Vanguard, èsì ikú yìí tí ilé-ìwòsàn ìjoba àpapó (National hospital) ní ìlú Abuja gbé jáde , fihàn pé ikú májèlé ni arabìnrin náà kú, látàrí egbò igi olóró tí a mò sí kokeènì (cocaine). Agbó wípé arabìnrin yìí ní àìsàn okàn tí a mò sí (cardiogenic shock).  Ìyá olóògbé ,Philomena Odama, ní ìbèrè pèpè osù ti ko ìwé èbè (petition) sí ipò ààre  orílè èdè (presidency), ìgbìmò asòfin àgbà (Senate president), agbenuso ilé ìgbìmò asojú sòfin (speaker of house of representative), ògá àgbà ilé-isé olóòpá (IGP) DSS àti àwon èyà tí o ń dáàbò bo ìlú pèlú àwon tí ó wà ní ipò gíga nípa ikú omo rè. Nínú ìwé tí aya Philomena ko o se àfihàn bí eni tí won fura sí yìí ti máa ń gbé òpòlopò omoge ní èbá ònà tí ó sì máa ń se ìlérí wípé òhun o tó won ní iié-ìwé.

    Ní àkámó eni tí a fura sí yìí ní arabìnrin Joy odama kú sí. Ó sì ti gbìmò pò mó àwon olóòpá láti gbé omo náà sínú yìnyín láì fi tó àwon òbí rè létí. Àwon olóòpá ní kí àwon jáwó nínú ejó náà kí àwon sì gba egbèrún lónà egbèédógún (300,000) tí a fura sí yìí gbé fún won. Wípé àwon kò sì le è dá ejó nítorí gbajúmò tí ó túmò sí wípé òtòkùlú ni…….English Version

 Continue bellowAutopsy report shows 200 level student of the Cross Rivers state University, Joy Odama, died of cocaine poison The autopsy report for Joy Odama, the 200 level student of the Cross River State University of Science and Technology, CRUTEC, who died mysteriously after she went to visit a certain Alhaji Usman Adamu, in Abuja last December, has been released. According to Vanguard, the autopsy report released by the National Hospital, Abuja, showed she died of acute cocaine poison. Joy was said to have suffered cardiogenic shock secondary to diffusion before she died. The report reads in part:“The cause of death was traced to cardiogenic shock secondary to diffusion, myocardial infaration secondary to possible acute cocaine poison.” Mother of the deceased, Philomena Odama, had earlier this month, petitioned the presidency, the senate president, Speaker of the House of Representatives, IGP, DSS and other top security agencies, over the death of her daughter. Mrs Philomena in her petition, indicated the the suspect had invited her daughter alongside other young girls to his house and promised to sponsor their education. Joy died in his custody and the suspect allegedly connived with the police to embalm her without her parents consent. The police allegedly told them to hands off the case and collect N300, 000 the suspect was offering them, saying they can not get justice as he is well connected in the society. -

No comments:

Post a Comment